Yoruba Descriptive Female Names/Titles. (Orúkọ Àpọ́nlé àwọn Obìnrin)
Yoruba Descriptive Female Names/Titles.
(Orúkọ Àpọ́nlé àwọn Obìnrin)
Aya – Wife
Ìyá Ààfin – Palace mother/A Mrs.
Aya Ọba (Ayaba) – Queen consort
Ìyá Ọba (Ìyọba) – Queen mother
Olorì – King’s wife
Omidan – Damsel / Young lady
Ọmọge – Younger fashionable lady
Ìyàwó – New bride
Yèyélúwà – Mother of prosperity
Ìyálé – First Wife
Erelú – Female executive of power
Ìyálọjà – Market Leader
Arábìrin – Female comrade
Àrẹ̀mọ – The first child (Female or Male)
Ìyálájé – Female commercial Leader
Abilékọ – Married woman
Adèlèbọ – An older married woman
Ìyálóde – Leader of all women
Wúndíá – A maiden lady